Back to Languages
Yoruba - Chapter 111
Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Verse 1
Owo Abu-Lahab mejeeji ti sofo. Oun naa si sofo
Verse 2
Awon dukia re ati ohun ti o se nise (iyen, awon omo re) ko si nii ro o loro (nibi iya)
Verse 3
O si maa wo inu Ina elejo fofo
Verse 4
Ati iyawo re, alaaaru-igi-isepe elegun-un, (o maa wona)
Verse 5
Igba-ope ponponran maa wa ni orun re (ninu Ina)